Ezra 3:11
11
Pẹ̀lú ìyìn àti ọpẹ́ ni wọ́n kọrin sí
Olúwa
:
“Ó dára;
ìfẹ́ rẹ̀ sí Israẹli dúró títí láé.”
Gbogbo àwọn ènìyàn sì fi ohùn ariwo ńlá yin
Olúwa
, nítorí tí a ti fi ìpìlẹ̀ ilé
Olúwa
lélẹ̀.
Copyright information for
YorBMYO