a
Jh 13.3
;
16.28
.
John 8:42
Àwọn ọmọ èṣù
42
a
Jesu wí fún wọn pé,
“Ìbá ṣe pé Ọlọ́run ni Baba yín, ẹ̀yin ìbá fẹ́ràn mi: nítorí tí èmi ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run jáde, mo sì wá; bẹ́ẹ̀ ni èmi kò sì wá fún ara mi, ṣùgbọ́n òun ni ó rán mi.
Copyright information for
YorBMYO